Posts

Showing posts with the label Q Dot

Q Dot feat Olamide - Ibadan lyrics

Bi sekere ba ti dun oo Konga a te le A te le Ijo ma tele Antrans ko gi le o fun mi jaree Verse 1: Lateko de challengi A gba guru mara ji Awole pelu bugati Ankara lori fasasi Idi n be nibadan o Oke be nibadan o Idi arere idi ayunre Oke sango oke mo po Ema je ko di ja Olosho yapa ni bodija o Pelu sokoto pe n pe Awon omo mi ni mo lete Ema soko fun eye twitter Alomo metta feya speaker Furo rabata fe ya bumber Them say them to buggi down Chorus: Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo re o Be wa deko be ba ni le Ibadan ni mo wa oo Verse 2: (Olamide) E shoutout si awon omo uni Leed city de badan poly Ebami ki kunle silencer Omo musulumi to fa poli Ero to lo london Ebami ki tayo dekida Tiringbeku teletele Omo ibadan to di nigga Omo woli to n fa taba Basira su sara ko ta ba Omugo fe high ogun lada Won de ni momo re feya fada Qdot fe silekun fe kun O yo tan owa be kun bekun I turn up tan osi seku Ka to fi embivadale le odi seven Chorus: Ibadan ni mo wa o Ibadan ni mo